IWE OGUN 2

 Ejinrin.ori ologbo ti sode, atare,ao kole lori jijo.


ORI okete gbegbe a o lo a fise eja aro ti la fun 're. A o iyere se lepe ni yo.


Ifun okete ewe ewuro a o fitele ape a o fibo pelu atare.


Ako alagba meta, ewura a o fi Tele ko le ao fi ewure bo. A o fi atare le a o fi ewura no, jijo lilo.


Ifun okete pelu ewe etiponola, etu ela, pelu imi ORUN, a o sa si iboji. A o mafin laro. Oko oloko ni okete ko.


Ose awure --egbo abifa ati ewe re, egungun olufa, egungun oka, ehaa okuku, ati ose dudu, lofinda ti a fe.ohun re-- Ibi oka ba si, ibi ere ba si lo onje won ba won,ibi lasso joko ni okuku too wa,


Ose awue---ewe titipoola,ewe omisimisi,adun,ose ati lofinda Olohun gidi,a o ko sinu awo amo. 


Comfort Ogundipe ao fi owo osi gba lemeeta, ao ma so wipe wegunwepe wegunwepe wegunwepe, we egun, we epe, we assasi, we abilu , to wa Lara mi danu, ao lo mo kahun bilala die pelu ose iwe ekan, ao gbele ao da iyo isebe sinu ile ti a gbe naa, ao fi ose na fo Ori wa sinu koto naa pelu adura.


Ewe osanketu (opa elesinrin)

Owulo fun afato ka gbo mimu, akele wu tegbotebo ka fi eyin adie kan tele kase kafi we a o je eyin yen, Asina awebi


Ewe awolu matee

Ogun awure ti odaju ni

Ao lo ja gure yi ni opolopo amo ako nipe ni gure nigbana ao pe ni awolumate ao gun ewe yi ni enu ona ti angba koja ao po lose eyikeyi ti oba wuwa ao fi oyi  po ose na dada ao ko si inu ike fun fun ijo ti aba fe kan kan we aje ijo alamisi ti oba di ijokeji tise ojo jimo ao ra ekuru fun fun laisi ata nibe ao se adura si ao fi wole ayika wa odaju 08107154122

Ewe gbomoyo

Popular posts from this blog

PALACE POSTS

SEE AS