COMMON HERBS ONE(KUJEKUJE APARO)
Mollugo Nullicaulis Lam
Kujekuje Aparo - Yoruba
Narba - Hausa
Naked stem chickened.
1. Iko ati otutu
A o se ewe kujekuje yi latike pelu atare. A o ma fin Simi ati ki a ma later lekokan lemeeta lojumo.
2. Iko Awubi ati seje nimu.
Bi atise ti iko ati tutu loke, be ni a o ti lo.
3. Iba Jefujefu.
A o lo ewe kujekuje yi pelu Alubosa Ayu, a o ma fi mu tea tabi eko gbigbona leemeta lojumo.
4. Iba Apatisan.
A o lo ewe kuje yi die mo milk tabi fifi alike ewe kujekuje so milk leemeta lojumo.
5. Arun oju.
A o ma fi omi ti a fun lati ara ewe kujekuje yi si ninu milk, a o ma man si oju naa ni gbogbo igba.
6. Arun awoo.
A o lo ewe kujekuje yi a o se ketepe (paste) si ara tabi ibi ti o ni abawon. Oowo ti yo ti yo fi tu oyun jade.